113.The Dawn

  1. Sọ pé: "Mo sá di Olúwa òwúrọ̀ kùtùkùtù
  2. níbi aburú ohun tí Ó dá
  3. àti níbi aburú òru nígbà tí ó bá ṣóòkùn
  4. àti níbi aburú àwọn (òpìdán) t’ó ń fẹnu fátẹ́gùn túẹ́túẹ́ sínú àwọn ońdè
  5. àti níbi aburú onílara nígbà tí ó bá ṣe ìlara